I no fit lie you, wetin my eye don see, ó pọ̀ gan (hm-hm)
So many good wey man don do, but na bad dem go talk (hm-hm)
Even Jesus Christ, the Lord, dem nail am for cross (hm-hm)
You no fit please everybody, ọmọ, o mọ p'ẹnu l'ẹbọ o
(It's not personal, rárá o)
Personal, rárá o, rárá o
No give me yawa o (yawa o), no give me yawa o, yawa o
Ọmọ arayé kala o, tí o bá wá sí owó, wọ́n máa japa o
Don't take it personal (ahn), owọ́ epo lọn bá'ni lá
(Hmm)
Mo ṣ'oríre méje-méje (hmm)
Orí mi, kó ma kọ́ blessing (hmm)
Credit alert (hmm)
Gratitude ṣa ni
Mo ṣ'oríre méje-méje (mọ ṣ'ori re)
Orí mi, kó má kọ́ blessing (orí mi)
Credit alert
Gratitude (ṣa ni)
It's not personal, rárá o (rárá o)
Personal, rárá o, rárá o
No give me yawa o (yawa o) no give me yawa o, yawa o
Ọmọ arayé kala o (kala), tí o bá sí owó wọ́n má japa o
Don't take it personal, owọ́ epo l'ọ́n bá'ni lá
(Hmm)
Mo ṣ'oríre méje-méje (orírẹ)
Orí mi, kó máa kó blessing (orí mi)
Credit alert
Gratitude ṣa ni
Mo ṣ'oríre méje-méje (mo ṣ'orirẹ)
Orí mi, kó má kó blessing (orí mi)
Credit alert
Gratitude (ṣa ni)