Tradução gerada automaticamente

exibições de letras 11

Idan

Qdot

Letra

Idan

Idan

Qudusi idán (2t sobre os beats)Qudusi idán (2t upon the beats)
Idán de verdade, idánIdán gangan, idán
Filho de Mọriamọ, idán (idán o-o)Ọmọ Mọriamọ, idán (idán o-o)
Qdot é meu nomeQdot l'orúkọ mí

Eles sabem que eu sou idán (idán)Wọn mòpé emi ni idán (idán)
Idán que brilha e reluz (idan)Idán tí ó wẹ tó ń dán (idan)
Qudusi idán (idán)Qudusi idán (idán)
Idán não para (idán)Idán kí dàn (idán)
Como a vibe em Lekki tá brilhando? (Idán)Báwo l'áyán Lekki ṣé ń dan? (Idán)
Experiência não é só amizade, idán (idán)Àdánwò o kin ńse ọrẹ idán (idán)
Dinheiro na mão com Palmpay (idán)Gbowó lọwọ Palmpay (idán)
Não vai pagar com Opay (idán)Ko fi sanwó Opay (idán)

Idán não pode dormir (idán)Idán o gbọdọ sùn (idán)
Porque Yanki não vai acordar cedo (idán)Tori Yanki o ni pẹ ji (idán)
Dinheiro de verdade é o que vale (idán)Owó olówó l'égún na (idán)
É verdade que Peller faz brilhar (idán)Ootọ ni Peller ńpá dan (idán)
Obesere responde ao Rei idán (idán)Obesere lóhùn lọ Ọba idán (idán)
Mas, idán de verdade tá na cara (idán)Sugbọn, idán gangan lonju idán (idán)
É o que Sọdiki tem na mente (idán)Oùn lomu Sọdiki ọgbọnn (idán)
Vai lá e faz a mágica acontecer (idán)Gan lọ gbà arodan fún dan (idán)

Vocês ainda estão fazendo a festa (idán)Ẹ wọn mì sì tàn omidan (idán)
Antes de acabar, aproveitem (idán)Kẹ to gbé tan le tan (idán)
Vamos dançar até cansar (idán)Ẹma jẹ dan mọ dan (idán)
Pra idán não dar trabalho pra festa (idán)Ki idán ma ṣẹrù fún omidan (idán)
Idán vai estourar tudo (idán)Idán wey slap popo (idán)
Idán não vai dormir (idán)Idán no dey sleep (idán)
Só o sono tá esperando por idán (idán)Na sleep dey wait for idán (idán)
Idán hoje tá cheio de grana (idán)Idán òní wówó kiri (idán)
Dinheiro sempre vai atrás de 'dán (idán)Owó ló má ń wa 'dán (idán)

Idán é o chefão (idán)Idán na him be the don (idán)
É por isso que idán tá tranquilo (idán)Na why idán dey sit down (idán)
Alhamdulillah (idán)Alhamdulillah (idán)
Eu sei que você já comeu isso (idán)Mo mọpé ẹ ti jẹ yẹn tán (idán)
A glória de Deus nunca acaba (idán)Ọlá Olùwà o kín tán (idán)
Meu brilho não vai se apagar (idán)Lamba mi o le tán (idán)
Em vez de idán cair na armadilha (idán)Kàkà ki idán jabọ sí kòtò (idán)
A luz vai brilhar (idán)Mọnamọna ma tàn (idán)

Idán é o chefão (idán)Idán na don (idán)
Idán é o grande chefão (idán)Idán na high don (idán)
Don Jazzy realmente respeita idán (idán)Don Jazzy gan bẹ'rù idan (idán)
Wole Soyinka nunca desrespeitou idánWọle Soyinka tio bẹ ru idán ni
Sua cabeça brilha (idán)Ori ẹ ma dán (idán)
Adan como um mágico (idán)Adan bi t'ogidan (idán)
New Edition, idán (idán)New Edition, idán (idán)
Fala e faz brilhar (idán)Fẹnu ro dan (idán)
Fala e faz a árvore brilhar (idán)Fẹnu wù igi odán (idán)

Não vou deixar eles me calar (idán)Ma ba wọn fẹnu lu gángan (idán)
Não olhe pra mim e me faça calar (idán)Ma wo ojú ko tọ fẹnu jù 'dan (idán)
Idán é mais que 'dan (idán)Idan ju 'dan lọ (idán)
Hoje é brilho, brilho, brilhoLoni yan-yan, yan-yan, yan
Ladrão fala, online estamos (idán)Olè sọrọ, online lowa (idán)
Frango, não pode voar como um pássaro (idán)Chicken, ò lè fò bi ẹyẹ àdán (idán)
É um sacrifício que Ifá faz (idán)Eku ni ifá ńjẹ (idán)
Adífá come carne de boi (idán)Adífá lonjẹ màlúù (idán)

Idán não é yahoo (idán)Idan no be yahoo (idán)
Idán que brilha (idán)Idán to ń dàn (idán)
De Bourdilon até Aso Rock (idán)From Bourdilon to Aso Rock (idán)
Jagabanu é idán (idán)Jagabanu ní idan (idán)
Eu conheço os verdadeiros idánMo mọ awọn idán gangan
IBD Dende, idánIBD Dende, idán
Filho de Egungbohun, idánỌmọ Egungbohun, idán
Ṣeyi Tinubu, idánṢeyi Tinubu, idán
Baddy Osha idánBaddy Osha idán

Lanre Typical, idánLanre Typical, idán
Não tem idán que não tenha carroKosi idán kàn ton tá mọto
Depois de Arowolo, idánLẹyìn Arowolo, idán
MC Oluọmọ, idánMC Oluọmọ, idán
Riliwanu Cooler, idánRiliwanu Cooler, idán
Rei Sheffield, idánỌba Sheffield, idán
Kunle Poly, idánKunle Poly, idán
Tafa Sego, idánTafa Sego, idán
Kazeemu Elesu, idánKazeemu Elesu, idán

Kapa Owoẹyẹ, idánKapa Owoẹyẹ, idán
Filho único, idánỌkanlọmọ, idán
Ajibola Pasuma, idánAjibola Pasuma, idán
Eu conheço Fẹmi Joro, eu conheço Fẹmi JaguarMo mọ Fẹmi Joro, mo mọ Fẹmi Jaguar
Abu Abel, idánAbu Abel, idán
Sammy Larry, idánSammy Larry, idán
Tarry Shiny, idánTarry Shiny, idán
Não somos de MushinAnọbi tiwa ni Mushin
Eu conheço Lawali em AbujaMo mọ Lawali l'Abuja

Eu sou amigo do Oníbà de IbàMo ṣe bà Oníbà of Ibà
Billique, idánBillique, idán
Maverick, idánMaverick, idán
Doctor Brown, idánDoctor Brown, idán
Bobrito, idánBobrito, idán
Eu conheço Wale ticketMo mọ Wale ticket
Kazzy colocou idán no carroKazzy lo fi idán sí mọto
Eniola Tizzle, idánEniola Tizzle, idán
Deus do Snipper, idánỌlọfin Snipper, idán

Meu irmão Bunmi ObakoyaẸgbọn mi Bunmi Obakoya
Tunla de Lagos, idánTunla of Lagos, idán
Eu conheço o Bispo na TurquiaMo mọ Bishop nílù Turkey
Eu conheço Dandy, eu conheço Otunba KashyMo mọ Dandy, mo mọ Otunba Kashy
Filho de Ayilara, palavras de filho do Rei KumasiỌmọ Ayilara mi, ọrọ pọ Ọmọba Kumasi
Ikorodu, diga boko, Alabi SpatarcuzIkorodu wa, say boko, Alabi Spatarcuz

Baba Rado, Qdot é meu nomeBaba Rado, Qdot l'oruko mi
2T sobre o popo o-o2T upon the popo o-o
(2T na mixagem)(2T on the mix)


Comentários

Envie dúvidas, explicações e curiosidades sobre a letra

0 / 500

Faça parte  dessa comunidade 

Tire dúvidas sobre idiomas, interaja com outros fãs de Qdot e vá além da letra da música.

Conheça o Letras Academy

Enviar para a central de dúvidas?

Dúvidas enviadas podem receber respostas de professores e alunos da plataforma.

Fixe este conteúdo com a aula:

0 / 500

Opções de seleção